Low Price Guarantee
We Take School POs
Jesu Akọni mi/Jesus My Hero: Yoruba Bilingual Translation
Contributor(s): Horelyk, Mariia (Illustrator), Williams, Michael (Editor), Abdulkareem, Prestige (Translator)

View larger image

ISBN: 1091393265     ISBN-13: 9781091393264
Publisher: Independently Published
OUR PRICE: $9.98  

Binding Type: Paperback
Published: March 2019
Qty:
Additional Information
BISAC Categories:
- Bibles | God's Word - Children
Physical Information: 0.07" H x 8.5" W x 11" L (0.24 lbs) 26 pages
Themes:
- Religious Orientation - Christian
 
Descriptions, Reviews, Etc.
Publisher Description:
Lẹyin Halloween ni ọdun to kọja, ọmọ mi Ivan, ọmọ ọdun meji ṣaa deede bẹẹrẹ si ni bẹru ẹmi adẹrubaniyan nigbati o ba wa ninu okunkun. O bẹẹrẹ si ni isoro lati sun laalẹ. Yio ji ni ọpọlọpọ igba- pẹlu omi ẹkun - yio maa wipe: "Adẹrubaniyan ...Ẹru n bami..."Nitori eleyi, emi ati ọkọ mi gbiyanju ni gbogbo ọna lati ṣalaye nipa Jesus Kiristi fun n sugbọn ko ye e. Nitoribẹ, mo pinnu lati ṣe iwe awọn ọmọde, eyi ti o mu u rọrun lati mọ ẹniti Jesu jẹ. Iwe naa ni a pe ni "Jesu Akọni Mi" nitoripe, O ku lori agbelebu fun ẹṣẹ wa ti O si GBA WA LA lọwọ iparun ayeraye. Oun ni akọni didara julọ Iwe naa jẹ abala marun (oju ewe mẹwa) nitoribẹ o se e ka ni alaalẹ fun awọn ọmọ wa. Ati wipe nigbati wọn ba dagba to o, wọn le e ka fun ra a wọn Jesu Akọni Mi sọrọ nipa agbara Jesu lori ẹẹru, aisan, ijaya ati awọn iwulo ojoojumọ wa (igbesi aye ile-iwe) - eyiti o niise pẹlu awọn ọdọ wa (ati awọn ti o dagba diẹ) ni ode oni ati ọjọ iwaju.After Halloween last year, my 2-year-old son, Ivan, developed a sudden fear of monsters and being in the dark. He started struggling to sleep. He would often wake up - in tears - saying: "monsters... I'm scared..." Following that, my husband and I regularly try to explain who Jesus Christ is to him but he doesn't understand. So I decided to make a children book, that simplifies who Jesus is. The book is called "Jesus My Hero" because he died on the cross for our sins and SAVED us from eternal damnation. He is the ultimate superhero The book is only 5 spreads (10 pages) long, so it can be read every night to our little ones. And when they're old enough, they can read it for themselves Jesus My Hero addresses Jesus' power in the matters of fear, sickness, anxiety and general everyday needs (i.e school life) - all which affect our young (and older) children in this day and age.
 
Customer ReviewsSubmit your own review
 
To tell a friend about this book, you must Sign In First!